Published online by Cambridge University Press: 11 August 2017
Oríkì Tìmì Munirudeen Adésọlá Lawal Láminísà (2007–)
Láminísà ọmọ kúdú-ǹdú tó sewé gẹ̀ru-gẹ̀ru
Ọ̀pọ̀lọ̀pọ̀ ògùn arumọ gàlè gàlè
Láminísà ní bobá lọ́pọ̀ ògùn
Láminísà ní bobá lékèé- kò ní jẹ́ kó jẹ́
Ọmọ pẹ̀rẹ̀ ńdi-ọ̀pẹ-ọ̀kọ̀ọ̀kan làá he-ìrà
Àgbà tó bá he méjì ló sòjóró
Ọmọ palé-ntogun-jìgan ntogun
Ọmọ-arógun mọ́-sàá-àrọ̀nì wọn ò fiyè ogun nù
Ọmọ àrọ̀nì tí kò gbélé, Olúkòyí-Kòsin mi ogun-ún lọ
Ọmọ ẹ̀sọ́ rógunjó jàgìnmì
Bí baba wọn bá tijí, etí ogun níí mórí lé
Ọmọ-Oníkòyí tí kìí gbọfà lẹ́yìn,
Iwájú ni baba won fií gbọta
Ọmọ-Oníkòyí tó gbọfa lẹ́yìn, ojo ló ṣe
Ọmọ ẹni tó kú nílé-tagbé rogun rèé sin
Ọmọ Tìmì Àgbàlé Ọlọ́fà-Iná
Ọmọ ẹ̀sọ́ Ìkòyí, ọmọ ajídá gbẹ̀du àkàlà
Laminisa, a leafy sweet potato
Enormous charms that intoxicates
Laminisa says: “if you have many charms
And you are not forthright; the charms would lose their efficacy”
A heritage of war-happy
Arọni, who always thinks of war
Arọni, who does not stay at home
Olukoyi, who does not cease to go to war
A heritage of war happy
When their father woke up
He headed to the war front
A heritage of Olukoyi, who would not be hit by bullets at the back
Their father would rather be hit by bullets in the chest
A heritage of Olukoyi who is shot at the back is a coward
A heritage whose corpse is taken to war front for burial
The child of Tìmì Àgbàlé Ọlọ́fà-Iná
A heritage of Ikoyi
The child of one who woke up to beat drum of war
Oríkì Tìmì Tìjání Ọládòkun Oyéwùsì (1976–2007)
Tìjání Ọládòkun Àjàgbé Oyéwùsì.
Ọmọ Àgbánrán gbá ke ń ja.
Ọmọ sọ’gbó di ilé.
Ọmọ sọ̀’gbẹ́ dì ìgboro, ọmọ s’àtàn d'ọjà.
Ọmọ sọ inú ìgbẹ́ di ìgbẹ́jọ́, ó dá ọmọ lẹ́kun à fojú di.
Ọmọ àrúnse kútà, órí ilé sí Mọ́sálásí, fìlà funfun, èwù funfun,
sòkòtò
funfun bí Olósà ńlá.
Ọmọ Lálémo, ọmọ ẹ̀sọ́ Ìkòyí, ọmọ dìílẹ̀ dogun, Ọmọ ọ̀-sùn lẹ́dẹ̀-la obìnrin
kàkà,
Ọmọ a pa ẹran kárí ayaba.
Ọmọ Oníkòyí, tó gbọ́ ohùn ogun yọ̀ sẹ̀sẹ̀,
Àgbọ́nrán Ìkọ̀tún o jà nífọ́n, o jà l’Éjìgbò,
O fi ẹnu òsà gbolẹ̀ aara,
To save this book to your Kindle, first ensure no-reply@cambridge.org is added to your Approved Personal Document E-mail List under your Personal Document Settings on the Manage Your Content and Devices page of your Amazon account. Then enter the ‘name’ part of your Kindle email address below. Find out more about saving to your Kindle.
Note you can select to save to either the @free.kindle.com or @kindle.com variations. ‘@free.kindle.com’ emails are free but can only be saved to your device when it is connected to wi-fi. ‘@kindle.com’ emails can be delivered even when you are not connected to wi-fi, but note that service fees apply.
Find out more about the Kindle Personal Document Service.
To save content items to your account, please confirm that you agree to abide by our usage policies. If this is the first time you use this feature, you will be asked to authorise Cambridge Core to connect with your account. Find out more about saving content to Dropbox.
To save content items to your account, please confirm that you agree to abide by our usage policies. If this is the first time you use this feature, you will be asked to authorise Cambridge Core to connect with your account. Find out more about saving content to Google Drive.